Jump to content

Ẹyẹ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn ẹyẹ
Temporal range: Late Jurassic–Recent, 150–0 Ma
Scarlet Robin, Petroica boodang
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Àjákálẹ̀:
Ìjọba:
Ará:
Subphylum:
Superclass:
(unranked) Amniota
(unranked) Archosauria
Ẹgbẹ́:
Ẹyẹ (Aves)

Linnaeus, 1758
Subclasses & orders

Àwọn ẹyẹ

Awon Eye wa eranko, sugbon eranko yi, o le fo, ati o le fo dada! Awa ni awon Eye yato: awon adaba, awon eyele, awon ayékòótọ́, ati awon eye idi! Awon eye idi won wa pataki, won wa orisirisi idi fun be. Awon eye idi, won ri dada, won ri igba merin daa jù awon èniyàn! Ati nitori awon ẹyẹ idi, won ni agbara, won gbé Aami ti Ogun lati awon akoko Babeli.

ẹyẹ idi wura

Awon eye idi fo kiakia, ti e ba wo awon eye idi ni iji lile, nigba gbogbo eniyan sọkun ati kigbe, nigba awon eranko lo si ibi ìṣápamọ́ kúrò lọ́wọ́ afẹ́fẹ́ àti ààbò kúrò lọ́wọ́ ìjì won ma fo ati fo ga, ati fo ga gan, [1] won ko ni iberu lati iji, won ko ni iberu lati ohunkohun. Won ko itẹ ẹyẹ ni òkè nla ati idagẹẹrẹ-okegiga.